IWULO ATI ANFAANI OYIN-IGAN

 1 OGUN OJU ; Ti Oju re ban se pin, tabi ti o nyun o, ti o pon . Po Oyin ati alubosa funfun po mo ara gained. Maa kan si oju mejeji.

 2. INU RIRUN ; Lo Ewuro po mo Oyin ma lo sibi meji lehin onje ale.

 3. EGBO ; Ewuro po mon Oyin ma fi si oju egbo na.

 4. EYIN OMODE ; Oyin Igan ati Omi Osan wewe mon ara gained. Ki o si enjoyable Omo na ni sibi kan lemeji lojumo lehin onje.

 5. IKO IFEE (TUBERCULUS); Lo Atare, Ayu, Iyo ati Orogbo pelu Oyin Igan sinu Igo. Agba sibi meji ni igba meta lojumo.

 6. AIRI ORUN SUN ; Maa mu Oyin Igan solar. Sibi meji lalale.

 7. AILERA NINU OSU OBINRIN ; Nkan osu to nse segesege tabi to dudu (STOMACHPAIN) Lo sibi Oyin Merinmerin ni Emerin lojumo.

 8 AROMOLEGUN ; Lo Ewuro po mo oyin Igan fi pa ibi ti on ro E. Ki o lo sibi meji li ojojumo ni owuro kutukutu.

 9 AKANDUN TABI EEWO(BOIL). Lo Ewa ati Kaun po mo Oyin Igan. Ma fira ibe.

 10. OGBE INU(ULCER); Maa mu sibi Oyin meta ni owuro kutukutu ni wakati kan ki o to jeun aaro.

 11. FUN ATO KIKI(SEMEN  BOOST); Po eyin tutu po mo Oyin sibi marun. Lo gbogbo re leekan naa.

 12. IKO EGBE ; Po Omi Igbin ati Oyin po mo ara gained .Sibi nla meta leemeta lojojumo. Omode sibi kan laaro ati lale.

 13. JEDIJEDI ; Lo efirin, Omi Osanwewe po mo Oyin Igan . sibi meta laro ati lale lojojumo.

 14. ARUN ETI ; Ti eti ba nse oyun tabi ti o nrin eniyan, fi omi gbigbona po iyo die ati oyin mo ara gained ma kan si eti mejeji laro ati lale.

 15. KOKORO ENU; Po Oyin Igan po mo Osan wewe fifo enu ni igba meta lojojumo.

 16. ILE GBIGBONA ; Lo ewuro po mo Oyin Igan fi pa gbogbo ara, mu sibi mejimeji, lemeta lojumo.

17. INU DIDUN LEHIN TO BINRIN BA BIMO; Obinrin naa yio malo oyin sibi mejimeji lemeta lojumo.

 18. OMO TI O NTO SILE; Ki o maa mu sibi Oyin Igan mejimeji solar titi tiko fi ni to sile mo.

 19. IKO; Lo orogbo ki o daa sinu Oyin Igan lehin na bere si laa tabi ki o maa lo sibi kookan ni wakati metameta. Omode sibi kekere.

20. Maafi Oyin Igan mu Ogi tabi Tea. O dara.

21.OGUN OJUPIPON; Ma kan oyin si lemeta loojumo.

 22. ARUNSU ; Lo ewe ejirin po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.

 23 .ATOGBE; Omi ewe ewuro po mo Oyin Igan sibi merin lemeta lojumo.

 24. ROPAROSE; Fi ito re lo Oyin Igan lale.

25. EJE RIRU; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lojumo laro ati lale.

26. OKO LILE; Ma fi ogede dudu sisè kan oyin je.

 27. OGUN EJE; Lo omunu ewuro po mo Oyin Igan sibi meta loojo,.

 28. INU RIRUN ; Po iyo mo Oyin Igan sibi meta lojumo.

 29. FUN ARA DIDAN ; Po Oyin Igan mo adiagbon ma fi pa ara.

30. FUN IFA RUN AGBON.; Po etu mo oyin igan ma fi pa.

 31.FUN KOKORO ; Lo eru awon ka imi ojo etu po mo oyin igan mafi pa ara.

 32. FUN ARAN ; Omi osan wewe po mo oyin igan sibi meta meta lojumo.

33.KI INU OBIRIN GBONA. Lo ayu po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.

34 FUN IBA REFUNREFUN; Lo ayu po mo omi osan wewe eyin ati oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.

35. BI INA BA JO ENIYAN; Ma fi oyin pa ni gbogbo igba.

36 BI OMI GBIGBONA BA DAJO ENIYAN. Ma fi oyin igan pa.

37. ALEFO LARA OMODE; Lo eru awon ka etu imi ojo po mo Oyin Igan ma fi pa ni gbogbo igba (mase te fo rara).

38. OGUN EJE; Omi csan wewe eyin tutu mo oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.

39. BI ARA BA UN GBONA:- Omi ewuro ti agbo la ifi omi si ale fi iyo gbo a po mon Oyin Igan sibi meji lee meta loju mo fi pa gbogbo ara.

40. BI INU BA DUN OBIRIN; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lee meta lojumo.

 41.OGUN ARUNSU ; Fi iyo gbo efirin po mo oyin igan sibi meta lee meta lojumo.

42.NKAN OSU OBIRIN TO UN SE SEGESEGE; Lo ayu po mo omi osan wewe ati oyin igan .sibi meta lee meta lojumo.

 43. OGUN ATOSI. Omi jaganyin ;kun die, ayu po mo Oyin Igan .sibi merin lee meta lojumo.

44.KI ENI TO BA NI ATOGBE; Ma fi Oyin Igan mu Ogi ati Tea.  O ma din sugar ku lara.

45.Ki eni to ba tile ni OGOJI ODUN Ma fi OYIN IGAN mu Ogi tabi Tea.

46. OGUN DIDIN ISANRA KU; Ki afi omi se haha agbado ki oma fi oyin igan mu bi tea ni aro ATI  lale.

47 Ki agbalagba ma lo oyin lati mu tea tabi ogi ni ara ro ,o ma jeki opolo jipepe….

49 iwulo  Oyin enjoyable opolo omo akeko…

  A o wa oyin gidi, omo akeko yio ma la sibi meta meta siwaju laro Toba koko ji ….

 50 Eni ti ko ri orun solar ko lo ra epo igi asufeyeje lodo awon alagbo,ko lo die Kuna po papo mo oyin .ma la sibi meji lale ..

_Jowo pin lori platifoomu elero pupo ki gained le je anfani Oyin( SOJ )

Hits: 11