zaykar

IWULO ATI ANFAANI OYIN-IGAN

*IWULO ATI ANFAANI OYIN-IGAN*

 *1 OGUN OJU ;* Ti Oju re ban se pin, tabi ti o nyun o, ti o pon . Po Oyin ati alubosa funfun po mo ara gained. Maa kan si oju mejeji.

 *2. INU RIRUN* ; Lo Ewuro po mo Oyin ma lo sibi meji lehin onje ale.

 *3. EGBO* ; Ewuro po mon Oyin ma fi si oju egbo na.

 *4. EYIN OMODE* ; Oyin Igan ati Omi Osan wewe mon ara gained. Ki o si enjoyable Omo na ni sibi kan lemeji lojumo lehin onje.

 *5. IKO IFEE* *(TUBERCULUS);* Lo Atare, Ayu, Iyo ati Orogbo pelu Oyin Igan sinu Igo. Agba sibi meji ni igba meta lojumo.

 *6. AIRI ORUN SUN* ; Maa mu Oyin Igan solar. Sibi meji lalale.

 *7. AILERA NINU OSU* *OBINRIN* ; Nkan osu to nse segesege tabi to dudu (STOMACHPAIN) Lo sibi Oyin Merinmerin ni Emerin lojumo.

 *8 AROMOLEGUN* ; Lo Ewuro po mo oyin Igan fi pa ibi ti on ro E. Ki o lo sibi meji li ojojumo ni owuro kutukutu.

 *9 AKANDUN TABI* *EEWO(BOIL).* Lo Ewa ati Kaun po mo Oyin Igan. Ma fira ibe.

 *10. OGBE INU(ULCER);* Maa mu sibi Oyin meta ni owuro kutukutu ni wakati kan ki o to jeun aaro.

 *11. FUN ATO KIKI(SEMEN  BOOST);* Po eyin tutu po mo Oyin sibi marun. Lo gbogbo re leekan naa.

 *12. IKO EGBE* ; Po Omi Igbin ati Oyin po mo ara gained .Sibi nla meta leemeta lojojumo. Omode sibi kan laaro ati lale.

 *13. JEDIJEDI* ; Lo efirin, Omi Osanwewe po mo Oyin Igan . sibi meta laro ati lale lojojumo.

 *14. ARUN ETI* ; Ti eti ba nse oyun tabi ti o nrin eniyan, fi omi gbigbona po iyo die ati oyin mo ara gained ma kan si eti mejeji laro ati lale.

 *15. KOKORO ENU;* Po Oyin Igan po mo Osan wewe fifo enu ni igba meta lojojumo.

 *16. ILE GBIGBONA* ; Lo ewuro po mo Oyin Igan fi pa gbogbo ara, mu sibi mejimeji, lemeta lojumo.

*17. INU DIDUN LEHIN TO BINRIN BA BIMO;* Obinrin naa yio malo oyin sibi mejimeji lemeta lojumo.

 *18. OMO TI O NTO SILE;* Ki o maa mu sibi Oyin Igan mejimeji solar titi tiko fi ni to sile mo.

 *19. IKO;* Lo orogbo ki o daa sinu Oyin Igan lehin na bere si laa tabi ki o maa lo sibi kookan ni wakati metameta. Omode sibi kekere.

20. Maafi Oyin Igan mu Ogi tabi Tea. O dara.

*21.OGUN OJUPIPON;* Ma kan oyin si lemeta loojumo.

 *22. ARUNSU* ; Lo ewe ejirin po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.

 *23 .ATOGBE;* Omi ewe ewuro po mo Oyin Igan sibi merin lemeta lojumo.

 *24. ROPAROSE;* Fi ito re lo Oyin Igan lale.

*25. EJE RIRU;* Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lojumo laro ati lale.

*26. OKO LILE;* Ma fi ogede dudu sisè kan oyin je.

 *27. OGUN EJE;* Lo omunu ewuro po mo Oyin Igan sibi meta loojo,.

 *28. INU RIRUN* ; Po iyo mo Oyin Igan sibi meta lojumo.

 *29. FUN ARA DIDAN* ; Po Oyin Igan mo adiagbon ma fi pa ara.

*30. FUN IFA RUN AGBON.;* Po etu mo oyin igan ma fi pa.

 *31.FUN KOKORO* ; Lo eru awon ka imi ojo etu po mo oyin igan mafi pa ara.

 *32. FUN ARAN* ; Omi osan wewe po mo oyin igan sibi meta meta lojumo.

*33.KI INU OBIRIN GBONA.* Lo ayu po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.

*34 FUN IBA REFUNREFUN;* Lo ayu po mo omi osan wewe eyin ati oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.

*35. BI INA BA JO ENIYAN;* Ma fi oyin pa ni gbogbo igba.

36 BI OMI GBIGBONA BA DAJO ENIYAN. Ma fi oyin igan pa.

*37. ALEFO LARA OMODE;* Lo eru awon ka etu imi ojo po mo Oyin Igan ma fi pa ni gbogbo igba (mase te fo rara).

*38. OGUN EJE;* Omi csan wewe eyin tutu mo oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.

*39. BI ARA BA UN GBONA:-* Omi ewuro ti agbo la ifi omi si ale fi iyo gbo a po mon Oyin Igan sibi meji lee meta loju mo fi pa gbogbo ara.

*40. BI INU BA DUN OBIRIN;* Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lee meta lojumo.

 *41.OGUN ARUNSU* ; Fi iyo gbo efirin po mo oyin igan sibi meta lee meta lojumo.

*42.NKAN OSU OBIRIN TO UN SE SEGESEGE;* Lo ayu po mo omi osan wewe ati oyin igan .sibi meta lee meta lojumo.

 *43. OGUN ATOSI.* Omi jaganyin ;kun die, ayu po mo Oyin Igan .sibi merin lee meta lojumo.

*44.KI ENI TO BA NI ATOGBE;* Ma fi Oyin Igan mu Ogi ati Tea.  O ma din sugar ku lara.

*45.Ki eni to ba tile ni OGOJI ODUN Ma fi OYIN IGAN mu Ogi tabi Tea.*

*46. OGUN DIDIN ISANRA KU;* Ki afi omi se haha agbado ki oma fi oyin igan mu bi tea ni aro ATI  lale.

*47 Ki agbalagba ma lo oyin lati mu tea tabi ogi ni ara ro ,o ma jeki opolo jipepe….*

*49 iwulo  Oyin enjoyable opolo omo akeko…*

  A o wa oyin gidi, omo akeko yio ma la sibi meta meta siwaju laro Toba koko ji ….

 *50 Eni ti ko ri orun solar* ko lo ra epo igi asufeyeje lodo awon alagbo,ko lo die Kuna po papo mo oyin .ma la sibi meji lale ..

*_Jowo pin lori platifoomu elero pupo ki gained le je anfani Oyin*( SOJ )

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *